Est 1:13 YCE

13 Ọba si bi awọn ọlọgbọ́n, ti nwọn moye akokò, (nitori bẹ̃ni ìwa ọba ri si gbogbo awọn ti o mọ̀ ofin ati idajọ:

Ka pipe ipin Est 1

Wo Est 1:13 ni o tọ