2. Sam 1:1 YCE

1 O si ṣe lẹhin ikú Saulu, Dafidi si ti ibi iparun awọn ara Amaleki bọ̀, Dafidi si joko nijọ meji ni Siklagi;

Ka pipe ipin 2. Sam 1

Wo 2. Sam 1:1 ni o tọ