2. Sam 2:14 YCE

14 Abneri si wi fun Joabu pe, Jẹ ki awọn ọmọkunrin dide nisisiyi, ki nwọn ki o si ta pọrọ́ niwaju wa. Joabu si wipe, Jẹ ki wọn ki o dide.

Ka pipe ipin 2. Sam 2

Wo 2. Sam 2:14 ni o tọ