2. Sam 3:18 YCE

18 Njẹ, ẹ ṣe e: nitoriti Oluwa ti sọ fun Dafidi pe, Lati ọwọ́ Dafidi iranṣẹ mi li emi o gbà Israeli enia mi là kuro lọwọ awọn Filistini ati lọwọ gbogbo awọn ọta wọn.

Ka pipe ipin 2. Sam 3

Wo 2. Sam 3:18 ni o tọ