2. Sam 3:36 YCE

36 Gbogbo awọn enia si kiyesi i, o si dara loju wọn: gbogbo eyi ti ọba ṣe si dara loju gbogbo awọn enia na.

Ka pipe ipin 2. Sam 3

Wo 2. Sam 3:36 ni o tọ