2. Sam 5:12 YCE

12 Dafidi si kiyesi i pe, Oluwa ti fi idi on mulẹ lati jọba lori Israeli, ati pe, o gbe ijọba rẹ̀ ga nitori Israeli awọn enia rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Sam 5

Wo 2. Sam 5:12 ni o tọ