18 Dafidi ọba si wọle lọ, o si duro niwaju Oluwa, o si wipe, Oluwa Ọlọrun, tali emi, ati ki si ni idile mi, ti iwọ fi mu mi di isisiyi?
Ka pipe ipin 2. Sam 7
Wo 2. Sam 7:18 ni o tọ