2. Sam 8:12 YCE

12 Lọwọ Siria ati lọwọ Moabu, ati lọwọ awọn ọmọ Ammoni, ati lọwọ awọn Filistini, ati lọwọ Amaleki, ati ninu ikogun Hadadeseri ọmọ Rehobu ọba Soba.

Ka pipe ipin 2. Sam 8

Wo 2. Sam 8:12 ni o tọ