2. Sam 8:3 YCE

3 Dafidi si kọlu Hadadeseri ọmọ Rehobu, ọba Soba, bi on si ti nlọ lati gbà ilẹ rẹ̀ pada ti o gbè odo Eufrate.

Ka pipe ipin 2. Sam 8

Wo 2. Sam 8:3 ni o tọ