2. Sam 8:5 YCE

5 Nigbati awọn ara Siria ti Damasku si wá lati ran Hadadeseri ọba Soba lọwọ, Dafidi si pa ẹgbãmọkanla enia ninu awọn ara Siria.

Ka pipe ipin 2. Sam 8

Wo 2. Sam 8:5 ni o tọ