Oni 1:13 YCE

13 Mo si fi aiya mi si ati ṣe afẹri on ati wadi ọgbọ́n niti ohun gbogbo ti a nṣe labẹ ọrun, lãla kikan yi li Ọlorun fi fun awọn ọmọ enia lati ṣe lãla ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Oni 1

Wo Oni 1:13 ni o tọ