Oni 10:3 YCE

3 Ati pẹlu nigbati ẹniti o ṣiwère ba nrìn li ọ̀na, ọgbọ́n rẹ̀ a fò lọ, on a si wi fun olukuluku enia pe aṣiwère li on.

Ka pipe ipin Oni 10

Wo Oni 10:3 ni o tọ