1. Kor 1:27 YCE

27 Ṣugbọn Ọlọrun ti yàn awọn ohun wère aiye lati fi dãmu awọn ọlọgbọ́n; Ọlọrun si ti yàn awọn ohun ailera aiye lati fi dãmu awọn ohun ti o li agbara;

Ka pipe ipin 1. Kor 1

Wo 1. Kor 1:27 ni o tọ