1. Kor 1:28 YCE

28 Ati awọn ohun aiye ti kò niyìn, ati awọn ohun ti a nkẹgàn, li Ọlọrun si ti yàn, ani, awọn ohun ti kò si, lati sọ awọn ohun ti o wà di asan:

Ka pipe ipin 1. Kor 1

Wo 1. Kor 1:28 ni o tọ