Ifi 12:5 YCE

5 O si bí ọmọkunrin kan ti yio fi ọpá irin ṣe akoso gbogbo awọn orilẹ-ède: a si gbà ọmọ rẹ̀ lọ soke si ọdọ Ọlọrun, ati si ori itẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ifi 12

Wo Ifi 12:5 ni o tọ