Ifi 13:7 YCE

7 A si fi fun u lati mã ba awọn enia mimọ́ jagun, ati lati ṣẹgun wọn: a si fi agbara fun u lori gbogbo ẹya, ati enia, ati ède, ati orilẹ.

Ka pipe ipin Ifi 13

Wo Ifi 13:7 ni o tọ