Ifi 14:8 YCE

8 Angẹli miran si tẹ̀le e, o nwipe, Babiloni wó, Babiloni ti o tobi nì wó, eyiti o ti nmú gbogbo orilẹ-ède mu ninu ọti-waini ibinu àgbere rẹ̀.

Ka pipe ipin Ifi 14

Wo Ifi 14:8 ni o tọ