Ifi 15:1 YCE

1 MO si ri àmi miran li ọrun ti o tobi ti o si yanilẹnu, awọn angẹli meje ti o ni awọn iyọnu meje ikẹhin, nitori ninu wọn ni ibinu Ọlọrun de opin.

Ka pipe ipin Ifi 15

Wo Ifi 15:1 ni o tọ