1 LẸHIN nkan wọnyi mo si ri angẹli miran, o nti ọrun sọkalẹ wá ti on ti agbara nla; ilẹ aiye si ti ipa ogo rẹ̀ mọlẹ.
Ka pipe ipin Ifi 18
Wo Ifi 18:1 ni o tọ