Ifi 18:11 YCE

11 Awọn oniṣowo aiye si nsọkun, nwọn si nṣọ̀fọ lori rẹ̀; nitoripe ẹnikẹni kò rà ọjà wọn mọ́:

Ka pipe ipin Ifi 18

Wo Ifi 18:11 ni o tọ