Ifi 19:11 YCE

11 Mo si ri ọrun ṣí silẹ, si wo o, ẹṣin funfun kan; ẹniti o si joko lori rẹ̀ ni a npe ni Olododo ati Olõtọ, ninu ododo li o si nṣe idajọ, ti o si njagun.

Ka pipe ipin Ifi 19

Wo Ifi 19:11 ni o tọ