Ifi 2:23 YCE

23 Emi o si fi ikú pa awọn ọmọ rẹ̀; gbogbo ijọ ni yio si mọ̀ pe, emi li ẹniti nwadi inu ati ọkàn: emi o si fifun olukuluku nyin gẹgẹ bi iṣẹ nyin.

Ka pipe ipin Ifi 2

Wo Ifi 2:23 ni o tọ