Ifi 20:13 YCE

13 Okun si jọ awọn okú ti mbẹ ninu rẹ̀ lọwọ; ati ikú ati ipo-okú si jọ okú ti o wà ninu wọn lọwọ: a si ṣe idajọ wọn olukuluku gẹgẹ bi iṣẹ wọn.

Ka pipe ipin Ifi 20

Wo Ifi 20:13 ni o tọ