Ifi 3:15 YCE

15 Emi mọ̀ iṣẹ rẹ, pe iwọ kò gbóna bẹ̃ni iwọ kò tutù: emi iba fẹ pe ki iwọ kuku tutù, tabi ki iwọ kuku gbóna.

Ka pipe ipin Ifi 3

Wo Ifi 3:15 ni o tọ