Ifi 7:4 YCE

4 Mo si gbọ́ iye awọn ẹniti a fi èdidi sami si: awọn ti a sami si jẹ ọkẹ́ meje o le ẹgbaji lati inu gbogbo ẹ̀ya awọn ọmọ Israeli wá.

Ka pipe ipin Ifi 7

Wo Ifi 7:4 ni o tọ