Ifi 9:2 YCE

2 O si ṣí iho ọgbun na; ẹ̃fin si ru jade lati inu iho na wá, bi ẹ̃fin ileru nla; õrùn ati oju sanma si ṣõkun nitori ẹ̃fin iho na.

Ka pipe ipin Ifi 9

Wo Ifi 9:2 ni o tọ