Ifi 9:6 YCE

6 Li ọjọ wọnni li awọn enia yio si mã wá ikú, nwọn kì yio si ri i; nwọn o si fẹ lati kú, ikú yio si sá kuro lọdọ wọn.

Ka pipe ipin Ifi 9

Wo Ifi 9:6 ni o tọ