Joh 1:19 YCE

19 Eyi si li ẹrí Johanu, nigbati awọn Ju rán awọn alufã ati awọn ọmọ Lefi lati Jerusalemu wá lati bi i lẽre pe, Tani iwọ ṣe?

Ka pipe ipin Joh 1

Wo Joh 1:19 ni o tọ