Joh 1:45 YCE

45 Filippi ri Natanaeli, o si wi fun u pe, Awa ti ri ẹniti Mose ninu ofin ati awọn woli ti kọwe rẹ̀, Jesu ti Nasareti, ọmọ Josefu.

Ka pipe ipin Joh 1

Wo Joh 1:45 ni o tọ