Joh 10:41 YCE

41 Awọn enia pipọ si wá sọdọ rẹ̀, nwọn si wipe, Johanu ko ṣe iṣẹ àmi kan: ṣugbọn otitọ li ohun gbogbo ti Johanu sọ nipa ti ọkunrin yi.

Ka pipe ipin Joh 10

Wo Joh 10:41 ni o tọ