9 Emi ni ilẹkun: bi ẹnikan ba ba ọdọ mi wọle, on li a o gbà là, yio wọle, yio si jade, yio si ri koriko.
Ka pipe ipin Joh 10
Wo Joh 10:9 ni o tọ