Joh 11:45 YCE

45 Nitorina li ọ̀pọ awọn Ju ti o wá sọdọ Maria, ti nwọn ri ohun ti Jesu ṣe, nwọn gbà a gbọ.

Ka pipe ipin Joh 11

Wo Joh 11:45 ni o tọ