55 Ajọ irekọja awọn Ju si sunmọ etile: ọ̀pọlọpọ lati igberiko wá si gòke lọ si Jerusalemu ṣiwaju irekọja, lati yà ara wọn si mimọ́.
Ka pipe ipin Joh 11
Wo Joh 11:55 ni o tọ