Joh 12:6 YCE

6 Ṣugbọn o wi eyi, ki iṣe nitoriti o náni awọn talakà; ṣugbọn nitoriti iṣe olè, on li o si ni àpo, a si ma gbé ohun ti a fi sinu rẹ̀.

Ka pipe ipin Joh 12

Wo Joh 12:6 ni o tọ