Joh 13:38 YCE

38 Jesu da a lohùn wipe, Iwọ o ha fi ẹmí rẹ lelẹ nitori mi? Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun ọ, Akukọ kì yio kọ, ki iwọ ki o to sẹ́ mi nigba mẹta.

Ka pipe ipin Joh 13

Wo Joh 13:38 ni o tọ