Joh 14:19 YCE

19 Nigba diẹ si i, aiye ki ó si ri mi mọ́; ṣugbọn ẹnyin ó ri mi: nitoriti emi wà lãye, ẹnyin ó wà lãye pẹlu.

Ka pipe ipin Joh 14

Wo Joh 14:19 ni o tọ