Joh 14:24 YCE

24 Ẹniti kò fẹràn mi ni ko pa ọ̀rọ mi mọ́: ọ̀rọ ti ẹnyin ngbọ́ kì si iṣe ti emi, ṣugbọn ti Baba ti o rán mi.

Ka pipe ipin Joh 14

Wo Joh 14:24 ni o tọ