Joh 15:13 YCE

13 Ko si ẹnikan ti o ni ifẹ ti o tobi jù eyi lọ, pe ẹnikan fi ẹmí rẹ̀ lelẹ nitori awọn ọrẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Joh 15

Wo Joh 15:13 ni o tọ