Joh 15:6 YCE

6 Bi ẹnikan kò ba gbé inu mi, a gbe e sọnu gẹgẹ bi ẹka, a si gbẹ; nwọn a si kó wọn jọ, nwọn a si sọ wọn sinu iná, nwọn a si jóna.

Ka pipe ipin Joh 15

Wo Joh 15:6 ni o tọ