Joh 18:33 YCE

33 Nitorina Pilatu tún wọ̀ inu gbọ̀ngan idajọ lọ, o si pè Jesu, o si wi fun u pe, Ọba awọn Ju ni iwọ iṣe?

Ka pipe ipin Joh 18

Wo Joh 18:33 ni o tọ