Joh 19:32 YCE

32 Nitorina awọn ọmọ-ogun wá, nwọn si ṣẹ́ egungun itan ti ekini, ati ti ekeji, ti a kàn mọ agbelebu pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin Joh 19

Wo Joh 19:32 ni o tọ