Joh 19:40 YCE

40 Bẹni nwọn gbé okú Jesu, nwọn si fi aṣọ ọ̀gbọ dì i pẹlu turari, gẹgẹ bi iṣe awọn Ju ti ri ni isinkú wọn.

Ka pipe ipin Joh 19

Wo Joh 19:40 ni o tọ