Joh 4:21 YCE

21 Jesu wi fun u pe, Gbà mi gbọ́, obinrin yi, wakati na mbọ̀, nigbati kì yio ṣe lori òke yi, tabi Jerusalemu, li ẹnyin o ma sìn Baba.

Ka pipe ipin Joh 4

Wo Joh 4:21 ni o tọ