Joh 5:21 YCE

21 Nitoripe gẹgẹ bi Baba ti njí okú dide, ti o si nsọ wọn di ãye; bẹ̃li Ọmọ si nsọ awọn ti o fẹ di ãye.

Ka pipe ipin Joh 5

Wo Joh 5:21 ni o tọ