Joh 5:28 YCE

28 Ki eyi ki o máṣe yà nyin li ẹnu; nitoripe wakati mbọ̀, ninu eyiti gbogbo awọn ti o wà ni isà okú yio gbọ́ ohùn rẹ̀.

Ka pipe ipin Joh 5

Wo Joh 5:28 ni o tọ