Joh 5:39 YCE

39 Ẹnyin nwá inu iwe-mimọ́ nitori ẹnyin rò pe ninu wọn li ẹnyin ni ìye ti kò nipẹkun; wọnyi si li awọn ti njẹri mi.

Ka pipe ipin Joh 5

Wo Joh 5:39 ni o tọ