Joh 6:15 YCE

15 Nigbati Jesu si woye pe, nwọn nfẹ wá ifi agbara mu on lọ ifi jọba, o tún pada lọ sori òke on nikan.

Ka pipe ipin Joh 6

Wo Joh 6:15 ni o tọ