Joh 6:24 YCE

24 Nitorina nigbati awọn enia ri pe, Jesu kò si nibẹ̀, tabi awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, awọn pẹlu wọ̀ ọkọ̀ lọ si Kapernaumu, nwọn nwá Jesu.

Ka pipe ipin Joh 6

Wo Joh 6:24 ni o tọ