Joh 6:31 YCE

31 Awọn baba wa jẹ manna li aginjù; gẹgẹ bi a ti kọ o pe, O fi onjẹ fun wọn jẹ lati ọrun wá.

Ka pipe ipin Joh 6

Wo Joh 6:31 ni o tọ