Mak 14:7 YCE

7 Nigbagbogbo li ẹnyin sá ni talakà pẹlu nyin, ẹnyin le ma ṣore fun wọn nigbakugba ti ẹnyin fẹ; ṣugbọn emi li ẹnyin kó ni nigbagbogbo.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:7 ni o tọ